EGBE YORUBA KAN FESUN KAN TINUBU,RIBADU BI WON SE KO OHUN IJAGUN IBON FUN AWON EGBE MIYETTI ALLAH
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-12-21
Просмотров: 7749
Описание:
EGBE YORUBA KAN FESUN KAN TINUBU,RIBADU BI WON SE KO OHUN IJAGUN IBON FUN AWON EGBE MIYETTI ALLAH
Ẹgbẹ Yorùbá kan bù ẹnu àtẹ lù Ààrẹ Tinubu ati Ribadu lórí kíkó àwọn ohun ijagun ibọn fún àwọn ẹgbẹ Miyetti Allah lasiko ikọlu lemọlemọ to n waye nipinlẹ Kwara ati Kogi
Ààrẹ Tinubu ti gbe àbá ètò ìṣúná o-le-ni triliọnu mejidinlọgọta naira N58.47trn ọdún 2026 lọ síwájú ilé aṣòfin fún ìbuwọ́lù
Àlàyé rèé o lórí bí obìnrin tí àwọn agbésùnmọ̀mí jí gbé ní Zamfara ṣe bímọ sákàtà wọn
Ariwo lasan o se o, Wọn kii jawe-olubori eto idibo lori ayélujára - Shettima lo sọrọ soke bẹẹ
Ẹ gbọ o, Ṣé lóòótọ́ làwọn kan ṣe pàṣípààrọ̀ òfin owó orí tuntun tíjọba Nàìjíríà fẹ́ bẹ̀rẹ̀ lọ́dún 2026?
Ariwo ta o lorileede South Africa latari bi iko Ọlọ́pàá orileede náà se yìnbọn pa ọmọ Nàìjíríà.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: