AWON AJINIGBE TUN TI JI KABIYESI MII GBE SALO NIPINLE KWARA - AWON AGBEBON SEKOLU S'AGO OLOPA L'ONDO
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-01-02
Просмотров: 1564
Описание:
AWON AJINIGBE TUN TI JI KABIYESI MII GBE SALO NIPINLE KWARA - AWON AGBEBON SEKOLU S'AGO OLOPA L'ONDO
Wọn tun ṣọọṣẹ laabi wọn o, awọn ajínigbé tún ti jí Kábíyèsí míì gbé salọ nipínlẹ̀ Kwara
Opẹ o, Anthony Joshua kúrò níléèwòsàn lẹ́yìn tórí kóoyọ nínú ìjàmbá ọkọ tó gbẹ̀mí ọ̀rẹ́ rẹ̀ méjì
Lórí ìlànà owó orí tuntun, kò sí à ń padà sẹ́yìn mọ o - Ààrẹ Tinubu lo sọrọ soke bẹẹ
.- Awakọ Anthony Joshua ti jade kuro l'ọgba ileewosan, o seese ko kawọ pọnyin rojọ lori iṣẹlẹ ìjàmbá burúkú naa
O ma se o, èèyàn mẹta jẹ sisekupa, èèyàn mẹjọ farapa bi awọn agbebọn se ṣekọlu s'ilu Nasarawa
Ìdí rèé o tí Abubakar Malami agbẹjọ́rò àgbà nilẹwa Naijiria tẹ́lẹ̀ fi n ganu ṣọdún tuntun lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Kuje
Dúkìá olowo iyebiye, ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mílíọ̀nù jóná, ẹ̀mí sùn níbi ìjàmbá iná méjì tó ṣẹlẹ̀ láàárín ọ̀sẹ̀ kan l'Eko
Ipaya-ibẹrubojo bẹ silẹ bi awọn agbebọn se ṣekọlu s'agọ ọlọpa l'Ondo
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: