IDAJO IKU F'AWON AJINIGBE-AGBEBON YOO TUN MU KI EETO-AABO TO MEHE BURUKU SII NILEWA - IJOBA TINUBU
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-12-22
Просмотров: 8097
Описание:
IDAJO IKU F'AWON AJINIGBE-AGBEBON YOO TUN MU KI EETO-AABO TO MEHE BURUKU SII NILEWA - IJOBA TINUBU
Ìdájọ iku f'awọn Ajinigbe-Agbebọn ati awọn Agbesunmọmi yóò tun mu ki eeto-ààbò to mẹhẹ buruku síi nilẹwa Nàìjíríà - Ijọba Tinubu lo sọ f'awọn aṣofin bẹẹ
Awọn aṣòfin le ma lọ s'ile, Akpabio lo rawọ ẹbẹ sí Ààrẹ Tinubu bẹẹ latari bi wọn se ko awọn Ọlọpa kuro lẹyìn wọn
Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mọ́kànlá tó há sí Burkina Faso ti gba ìtúsílẹ̀ o
Kò ní sí ojúṣàájú tàbí ọ́wọ́ òṣèlú nínú yíyan Awujalẹ tile Ijebu tuntun o ke ya lo gbo seti - Gómìnà Abiodun lo so be
Gbajumọ akansẹkubiojo AnthonyJoshua fi ẹ̀ṣẹ́ rán Jake Paul lọ sílé ìwòsàn, leyin to kan legungun ẹ̀rẹ̀kẹ́ lásìkò ìjà ẹ̀ṣẹ́ kíkàn.
Ẹgbẹ Ajafetọọmọniyan ke gbajare sita lori ète ikọlu tuntun l'akoko pọpọsinsin ọdún kérésìmesì, wọn ni ki Tinubu dàbobo awọn èèyàn alainile-lori ati awọn ṣọọṣi
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: