AWON OLOOGUN LE AWON ONISESE KURO NIBI ETO ISINKU AWUJALE TO WAYE - DRIVETV YORUBA NEWS
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-07-15
Просмотров: 13822
Описание:
AWON OLOOGUN LE AWON ONISESE KURO NIBI ETO ISINKU AWUJALE TO WAYE - DRIVETV YORUBA NEWS
Oku Ààrẹ ilẹwa tẹlẹri, Muhammadu Buhari wọ kaalẹ sun, Awọn olubanikẹdun n sedaro
Ọba ba lori ohun gbogbo, Awọn ọba tó pẹ lórí ìtẹ́ nilẹ Yorùbá ní wọnyi
O ma se o, Èèyàn mẹrin pàdánù ẹmi wọn, awọn meje farapa latari bi ile akọpati alaja mẹta kan se dawo-lulẹ nipinlẹ Kano
Ileesẹ Ọlọpa doola awọn ọmọ Orilẹede Ghana mọkandinlogoji, at'awọn miiran ni ìgbèkùn awọn afèèyàn s'owo ẹru
"Ijiya yi pọ, Ẹ gbawa o" - Awọn Akẹkọ̀ọ́ akanda ẹda ni ọgbà Blind Centre l'Ogbomọsọ gúnlè iwọde-ifẹhonuhan takò awọn alaṣẹ Ileewe wọn latari aisi-amojuto to péye fún àwon akẹ́kọ̀ọ́
Awọn olóògùn le awọn onísẹ̀se kuro nibi eto ìsìnkú Awujale to waye, Ohun tí Awujale ṣe nígbà ayé rẹ̀ nípa eto ìsìnkú àwọn ọba rèé, táwọn oníṣẹ̀ṣe kò fi kópa níbi ìsìnkú rẹ̀
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: