OBA AWUJALE ILE IJEBU WO KAALE SUN- TINUBU,ATIKU,MAKINDE OONI IFE ATI AWON EEKAN ILU SE IDARO BUHARI
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-07-15
Просмотров: 9541
Описание:
OBA AWUJALE ILE IJEBU WO KAALE SUN - TINUBU,ATIKU,MAKINDE OONI IFE ATI AWON EEKAN ILU SE IDARO MUHAMMADU BUHARI - DRIVETV YORUBA NEWS
Ikú pa abírí, abírí ku, ikú pa abìrì abìrì r'ọrun o, Kabiesi Awujalẹ ilẹ Ijẹbu, Ọba Sikiru Kayode Adetọna, waja lẹni ọdun mọkanlelaadọrun, (91), o wọ kaalẹ sun l'ọjọ Aje Mọnde nilana ẹsin mùsùlùmí
Ààrẹ Tinubu, Atiku, Makinde, Ọọni ile Ifẹ àti àwọn èèkàn ìlú n ṣe ìdárò ààrẹ ana, Muhammadu Buhari
Ìrẹ̀lẹ̀, Ìfọmọ-nìyànse, kiise ohun t'eeyan n fẹnu polongo o, inu iwa ati ise ni, Peter Obi lo sọrọ soke bẹ tako ohun t'awọn eeyan nsọ fun b'ose pin ounkẹ kiro loju agbo.
Itan igbesi aye Awujale ilẹ̀ Ijẹbu, Ọba Sikiru Kayode Adetona, tó wàjà
Àjọ alagbata epo nilẹwa Nàìjíríà IPMAN ti kede ìgbésẹ rẹ lati mu adinku ba iye ti wọn n ta epo bẹntiroolu
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: