ATOTO ARERE: OWO ILE TI GA LA GAJU O, AWON ARA IPINLE EKO KE GBAJARE.
Автор: Western Spring Television NG
Загружено: 2026-03-02
Просмотров: 60
Описание:
Iye owo ile n’Ípínlẹ̀ Lagos State ti di koko to n dun l’okan fun opolopo ara ilu. Lati Ikeja de Eti-Osa, lati Surulere de Ikorodu, iye owo yiyalo ile ati rira ile ti fo soke ju ti tele lo.
Opolopo ara Eko n ke gbajare. Diẹ ninu wọn n san ida to ju ida meji ninu owo osu won fun ile nikan. Beeni ibeere kan wa: kini o n fa ilosoke yii? Ati tani yoo daabo bo awon oniyalo?
#IleNiEko #LagosHousing #IyeOwoIle #EkoOniBaje #HousingCrisis #LagosState #IsoroAje #PublicAffairs
We explore the front pages of Nigeria's top dailies, providing background stories and expert insights on the latest happenings. Stay tuned for more updates on Western Spring Television, StarTimes Channel 190, and Startimes DTT. 📞
Participate live via: Phone: 091-3259-9000 WhatsApp: 091-3259-9000 🔊
Don’t miss a beat! Like, share, and subscribe to stay updated. Stay tuned for more updates on Western Spring Television, StarTimes Channel 190. For sponsorship and advertisement inquiries, call 0807-961-3963. / @westernspringtv 📢 Sponsorship & Ads: Contact 080-94-4453 for sponsorship and advert placement opportunities. Partner with us!
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: