AWON AGESUNMOMI KO LETA, BEERE FUN OWO ITANRAN OGORUN MILLIONU NAIRA
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-02-21
Просмотров: 3941
Описание:
AWON AGESUNMOMI KO LETA, BEERE FUN OWO ITANRAN OGORUN MILLIONU NAIRA #100M S'ILU KEBBI
B'awọn aráàlú se dojukọ awọn Agbesunmọmi Lakurawa funrawọn lo ṣokunfa iku awọn olùgbé-ilu mẹtalelọgbọn 33 naa nipinlẹ Kebbi - Ileesẹ Ọlọpa lo sọrọ soke bẹẹ
Ìjọba fẹ̀sùn kan ẹgbẹ́ alákatakítí ẹ̀sin Islam pé wọ́n ṣekúpa èèyàn mẹrinlelọgbọn 34 ní àwọn abúlé káàkiri
Ileesẹ Ọlọpa Enugu y'abo ibuba awọn ọdaràn, fi gbooro ofin gbe awọn Afurasí mẹẹdogun, wọn rí awọn ohun ijagun ibọn gba pada
Ileẹjọ pàṣẹ f'ajọ INEC lati f'orukọ NDP naa silẹ gẹgẹ bí ẹgbẹ oṣelu
Awọn agbesunmọmi kọ lẹta s'ilu Kebbi, wọn n bèèrè fún owó ìtanràn ọgọrùn milliọnu naira N100m
Ileesẹ olóògùn nawọ gan awọn alabaṣiṣẹpọ to n fi àwọn ohun elo sọwọ s'awọn ìkọ agbesunmọmi Boko-Haram, wọn rí awọn ohun ijagun ibọn, duronu gba kuro lọwọ wọn
Wọnyi l'àwọn ohun tuntun tó wà nínú òfin ètò ìdìbò tí Ààrẹ buwọ́lù
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: