ODALE NI JIDE KOSOKO, EMI NI OLOJA ILU EKO TI WON YAN - ABIOLA OLOJO - KOSOKO
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-02-17
Просмотров: 3907
Описание:
ODALE NI JIDE KOSOKO, EMI NI OLOJA ILU EKO TI WON YAN - ABIOLA OLOJO - KOSOKO
Ìjọba àpapọ̀ ti kọminú o lórí bí àwọn ọmọ Naijiria kan ṣe ń lọ jagun nílẹ̀ òkèrè láì mọ̀.
O ma wa ga o, awọn agbébọn tun sekọlu si ìlú mẹ́ta ní Niger, ṣekúpa èèyàn Ọgbọn, dáná sun ilé àti àgọ́ ọlọ́pàá nipinlẹ Niger.
Ìkọ Amọtẹkun nawọ gan awọn Afurasí Ajinigbe mejila, at'awọn metalelọgọrin mii l'Ondo
Haa! Èèyàn mẹrin jẹ jijigbe salọ ninu ikọlu tuntun mii nilu Kwara
Lowuro ojọ Aje Monday oko ero bus to n ko eja odo rinrin ajo ni ìjàmbá lopópónà Ogbomoso s'Oyo opọ dukia sofo pẹlu emi èèyàn.
Ọdàlẹ ni Jide Kosoko, Emi ni Oloja Ilu Èkó tí wọn yan - Abiola Olojo-Kosoko.
Ìjọba àpapọ̀ gbé El-Rufai lọ iléẹjọ́ lórí ẹ̀sùn titọwọbọ ibanisọrọ ori fóònù Nuhu Ribadu
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: