OPE O, AWON OLUFARAKASA METADINLOGOJI TI WON JI NIPINLE KASTINA TI RI ITUSILE GBA
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-11-30
Просмотров: 7768
Описание:
OPE O, AWON OLUFARAKASA METADINLOGOJI TI WON JI NIPINLE KASTINA TI RI ITUSILE GBA
A ní ìwé ilẹ̀ ìjọba ti a gba o amo síbẹ̀, ìjọba fẹ́ fowo ola gba wa loju won fe lé wa lórí ilẹ̀ wá- Ọ̀kan lára àwọn tọ́rọ̀ kàn lo soro soke bee
.- Mi ò lè pe ohun tó wáyé ní Guinea- Bissau je ìdìtẹ̀gbàjọba bikose pe o lọwo oselu ninu - Goodluck Jonathan lo salaye orọ náà
Haa! Èèyàn mẹta pàdánù ẹmi wọn ninu ìjàmbá ọkọ tanka epo to bugbamu ni Kano
Ọpẹ o, awọn Olufarakasa mẹtadinlogoji ti wọn ji nipinlẹ Katsina ti ri itusilẹ gba
Ìkọ Ọlọpa sekupa adigunjalè kan, fi gbooro ofin gbe awọn mẹta lásìkò ti idigunjale wọn já s'ofo ni Jigiwa
Ebi ojojoagba-fọwọ-mẹkẹ wọle dé fawọn Agbesunmọmi bi ìkọ ọmọ ogun se gba awọn apo ati pálí ẹja yiyan ti awọn ọlọja mejilelogun fẹ lọ ko fun awọn Agbesunmọmi nigbekun wọn ni Borno
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: