WAHALA! WON NI WASIU AYINDE KI SE OMO IDILE FUSENGBUWA TO N PE ARA RE,TO FI LOUN FE DUPO OBA AWUJALE
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-12-08
Просмотров: 8852
Описание:
WAHALA! WON NI WASIU AYINDE KI SE OMO IDILE FUSENGBUWA TO N PE ARA RE,TO FI LOUN FE DUPO OBA AWUJALE
Ọrọ bulẹgbẹ o, wọ́n ní Wasiu Ayinde kì í ṣe ọmọ ìdílé Fusengbuwa tó n pe ara rẹ̀, to fi loun fẹ dupò Ọba Awujalẹ
Ijọba ipinlẹ Kwara ẹ dakun ẹ gba wa, Ileesẹ Ọlọpa ko gbe ìgbésẹ kankan láti ìgbà tí wọ́n ti jí Ọba wa gbé salọ, àwa nìkan là ń sá kiri – Mọ̀lẹ̀bí Ọba tí wọ́n jí gbé salọ lo ke gbajare sita bẹẹ
Ọpẹ o, Ìjọba àpapọ̀ kéde itusilẹ awọn ọgọrun akẹ́kọ̀ọ́ 100 nínú àwọn tí wọ́n jí gbé salọ níleewe St Mary Catholic, Papiri nipinlẹ Niger
Ohun ìyanu rere ń bọ̀ nínu ìsejọba Tinubu, gbogbo ọ̀tá rẹ̀ ni ojú yóò tì - Aya Ààrẹ, Remi Tinubu lo sọrọ soke bẹẹ
Iwaadi-ifinmufinlẹ lori ijinigbe ọmọbìnrin àlùfáà oludasilẹ ìjọ Jesus is King sí n lọ lọwọ - Alukoro Ileesẹ Ọlọpa Ọyọ lo sọrọ soke bẹẹ
Eyikeyi onisowo POS to ba ko tí kò fi orúkọ sílẹ̀ yóò kan ìjàngbọ̀n lọ́dọ̀ ajo CBN, idi e ati ona to gbà kàn Opay àti Moniepoint re
Ìmò tú, ìmò jo, ìmọ̀ ibi kan e dọjọ́ alé, ìmọ̀ àwọn ológun láti dìtẹ̀gbàjọba Benin Republic forí sánpọ́n.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: