HAA! INA SEYO LAAFIN EMIR - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-03-02
Просмотров: 4515
Описание:
HAA! INA SEYO LAAFIN EMIR - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY
Mo kabamọ pe mo jẹ ọkan lara awọn to da ẹgbẹ oṣelu olosusuọwọ APC silẹ - Atiku lo sọrọ soke bẹẹ
Haa! Ina sẹyọ láàfin Emir Jama'a ni Kaduna
Àwọn Agbebọn tun ṣọọṣẹ laabi wọn o, wọn ji ọpọ olùgbé-ilu Kogi nitosi Ileewe Government Technical College gbe salọ
Ọdọmọdekunrin kan ganu s'atimọle Ọlọpa fẹsun fifipa ba Ọdọmọdebinrin lajọsepọ
Mo di alagbe- ẹni to n tọrọ jẹ lẹyìn ìjàmbá ina - Ọkunrin Eko kan lo kọminu bẹẹ
Ẹ tu ìgbéyàwó wa ka o- Ọkọ mi ma n fi ẹsun asemase kan mi, niiṣe lo ma n lù mí, tari mi jade sita ninu otutu l'alẹ - Iyawo kan lo rọ ileẹjọ bẹẹ
“Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí”
“The Voice of Yoruba Worldwide”
DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis.
We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada.
Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: