A KO NI JUWO SILE FUN IBERU "NO RETREAT NO SURRENDER" - AARE TINUBU FOWO SOYA - YORUBA NEWS TODAY
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-03-17
Просмотров: 5650
Описание:
A KO NI JUWO SILE FUN IBERU "NO RETREAT NO SURRENDER" - AARE TINUBU FOWO SOYA - YORUBA NEWS TODAY
Eyi tun ga o, Àwọn afurasí agbébọn yín àdó olóró tí kò lóǹkà, sekupa opọ eeyan, ba ọpọ dukia je nigbati awọn èèyàn bi 108 si farapa yanna yanna nipinle Borno
A kò ní juwọ́ sílẹ̀ fún ìbẹ̀rù — Ààrẹ Tinubu fọwọ́ sọya bẹẹ
Kwankwaso korooju si ibugbamu ado oloro to waye ni Maiduguri, o pe fún ìgbésẹ takò awọn Agbesunmọmi
Awọn èèyàn ti yóò dibo lo ni pàdánù ẹ̀mí wọn yi, Eto aabo lo yẹ ko jẹ kókó ohun tí ìjọba àpapọ̀ yóò mú lọkunkundun julọ, Kiise eto ìdìbò ọdún 2027 - Ndume lo ta bana ọrọ naa sígboro ayé bẹẹ
Yẹ̀yẹ́ ni wọn fi mi ṣe o nígbà tí ọmọ mi padanu ẹmi rẹ torí mo ṣe àtìlẹyìn fún Tinubu – Remi Surutu lo sọrọ jade bẹẹ
Obìnrin Eko kan f'ẹjọ kan Peller, lo ba tun bèèrè fún N395m lori ẹsun ibanilorukọjẹ ati ilòdì sí ìpamọ́ ẹni
Ti ki ba s'Ogunwuyi ta tun leni náà to le gbégẹsi tẹsiwaju isejọba Omi Tuntun to n tu awọn èèyàn lara dọkan nipinlẹ Ọyọ.
A ti sekupa Olori àwọn oṣiṣẹ aláàbò Ilẹ Iran, Ali Larijani - Ilẹ Israel lo sọrọ jade bẹẹ
Sent 6h a
“Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí”
“The Voice of Yoruba Worldwide”
DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis.
We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada.
Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: