ILEESE OLOPA TI FI GBOORO OFIN GBE AWON IKO AMOTEKUN OGUN NIYE LATARI ISEKUPANI NILU,NIPINLE OSUN
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-10-10
Просмотров: 9476
Описание:
ILEESE OLOPA TI FI GBOORO OFIN GBE AWON IKO AMOTEKUN OGUN NIYE LATARI ISEKUPANI NILU,NIPINLE OSUN
Ileesẹ Ọlọpa ti fi gbooro ofin gbe awọn ìkọ amọtẹkun ogun niye látàrí isekupani nilu, nipinlẹ Ọsun
Haa o mase o, ileesẹ ologun fidi iroyin iku ọkan lara wọn Samson Haruna tiyawo rẹ dana sun mulẹ .
Ẹjọ ti mo ba ro, are ni o, Adunni Ade bori ninu ẹjọ ti o pe tako ẹsun pe oun ati Dino n gbekan si n kan funra wọn
Christopher Kolade, àgbàọ̀jẹ̀ aláàkóso, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ dágbére f'aye lẹni ọdún mejilelaadọrun, Ààrẹ Tinubu, ati àwọn èèyàn jakanjakan lágbáyé ń se dárò olóògbé
Ẹ sì Ileesẹ ìkọ amọtẹkun pada - Ile igbimọ asofin ipinlẹ Ọsun pàṣẹ ki wọn sì ilẹkùn ọfisi amọtẹkun ti wọn gbe ti pa pada ni kiamọsa
Irọ ni o - Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní kó si ẹ̀rí majeminso láti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé agbénipa kọlú ọ̀gá agba Àmọ̀tẹ́kùn l'Ọsun
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: