HAA! AWON AGBESUNMOMI GE ORI AGBE KAN BOLE, SO INA SI AAFIN NIPINLE BORNO - DRIVETV YORUBA NEWS
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-10-01
Просмотров: 4332
Описание:
HAA! AWON AGBESUNMOMI GE ORI AGBE KAN BOLE, SO INA SI AAFIN NIPINLE BORNO - DRIVETV YORUBA NEWS
Haa! awọn agbesunmọmi ge ori àgbẹ kan bọlẹ, sọ ina si ààfin nipinlẹ Borno
Pasitọ ẹni ọdún mẹtalelọgọta 63 ganu s'ẹwọn fẹsun pe o fi tipa ba awọn ọmọ iya meji l'obinrin lajọsepọ nipinlẹ Enugu
Ọwọ tẹ wọn o, Àwọn agbófinró yabo ibùba àwọn agbébọn ni Kwara, sekupa ọpọ àwọn Ajinigbe-Agbebọn
Ẹ gbọ awọn kókó ọ̀rọ̀ tí ààrẹ Tinubu bá ọmọ Nàìjíríà sọ bí Nàìjíria se n s'àyájọ́ ọdún òmìnira
Ijọba ipinlẹ Eko fi Mandy Kiss jẹ Ambassador agbogunti ilokulo oogun oloro anti-drug abuse*
Aáwọ̀ PENGASSAN àti ibùdó ìfọpo Dangote gba ọ̀nà míì yọ, ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ń palẹ̀mọ́ mọ́ fún ìyanṣẹ́lọdì
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: