E WA GBO O, KI LO N SOKUNFA B'AWON OLUBADAN SE N WAJA LERALERA ATI IDI TI IBADAN SE N JE AGBOTIKUYO
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-07-09
Просмотров: 21132
Описание:
E WA GBO O, KI LO N SOKUNFA B'AWON OLUBADAN SE N WAJA LERALERA ATI IDI TI IBADAN SE N JE OMO AGBOTIKUYO
Ẹ wa gbọ o, ki lo n ṣokunfa b'áwọn Olubadan se ń wàjà léraléra àti ìdí tí Ibadan ṣe ń jẹ́ Ọmọ Agbọ́tikúyọ̀?
Oye ọba jijẹ nilẹ Ibadan ko ruju rara, ẹni to kan yoo ti mọ ara rẹ ṣaaju akoko ti yoo debẹ - bẹẹ l'ọrọ ri fún Rasheed Ladoja to n gbaradi lati di Olubadan ikẹrinlelogoji
Awakọ kan re o, o gún ọga rẹ tẹlẹri pa dojú iku nipinlẹ Eko
Wọn da ororo gbona lù arákùnrin kan lára fẹsun pe o jale l'ọja Eko
Ẹni ori yọ o d'ile o, awọn jàǹdùkú ṣekọlù s'ààfin, já ìlẹ̀kùn, ṣe ẹ̀ṣọ́ aláàbò léṣe, ba ọ̀pọ̀ dúkìá àti ọkọ̀ ọlọ́pàá jẹ́
Agbarijọpọ ẹgbẹ alatako ADC yoo fọ tuutu- yóò daru láàrin oṣù mẹfa - Ileesẹ Ààrẹ lo sọko ọrọ bẹẹ
Ẹgbẹ Igbo n pe fún ìgbésẹ kanmọkobo takò ikọlu awọn adaranjẹ l'apa ẹkun gúúsù-ìlàòrùn.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: