SE OGUN NI KADARA? OTITO NIPA AYANMO ATI KADARA || WOLI AJILORE ATAMATASE FOGBA YANGA
Автор: Ajilore Atamatase Prayer Live
Загружено: 2026-03-13
Просмотров: 153
Описание:
#SeOgunNiKadara #WoliAjilore#yorubaspirituality #Kadara #OgunAtiKadara
#YorubaMessage #nigeriaprophecy
Se ogun ni kadara gaan ni?
Ninu fidio yi, Woli Ajilore Atamatase n ṣalaye otito nipa ogun, ayanmo, ati kadara ninu aye eniyan. Ọ̀pọ̀ eniyan maa n ro pe ogun ni o n dari ayanmo eniyan, sugbon nibi yi a o gbo itumọ gidi ati bi a ṣe le ye kuro ninu ipa ogun.
Wo fidio yi titi de opin ki o le mo otito nipa kadara ati agbara ti ogun le ni lori aye eniyan.
👉 Ma gbagbe lati:
👍 Like
💬 Comment
🔔 Subscribe fun awon fidio ijinle miran.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: