Ojú Kálé: Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Sọ̀rọ̀ Lórí Òfin Owó-Orí Tuntun Tí Ìjọba Àpapọ̀ Kéde
Автор: Punch Newspapers
Загружено: 2026-01-11
Просмотров: 62
Описание:
A bá àwọn ará ìlú sọ̀rọ̀ nípa ohun tí wọ́n rí sí òfin owó-orí tuntun tí ìjọba àpapọ̀ kéde pé ó ti bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní, ọdún 2026.
Ọ̀pọ̀ mẹ̀kúnù ló fariwo ta pé òfin náà kò yé àwọn tó rárá, nígbà tí àwọn mìíràn sì rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba pé kí wọ́n fi gbogbo owó tí wọ́n ń gbà jọ náà ṣe ohun mèremère amáyédẹrùn sínú ìlú fún ìgbádùn gbogbo ọmọ ìlú, pàápàá jùlọ, àwọn mẹ̀kúnnù
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: