ITAN ILU IWERE ILE
Автор: Isedale Abinibi Wa
Загружено: 2021-12-13
Просмотров: 2966
Описание: Kò ṣeé ṣe láti sọ ìtàn Àláàfin Aólẹ̀ àti Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò Àfọ̀njá láì mẹ́nuba ìtàn ìlú Ìwéré ilé. Àwọn ohun tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa ìlú yìí bí: (Ohun tí ó bí orúkọ ìlú yìí, àwọn èèwọ wọn, ìdí tí ogun kìí fi í jà wọ́n, Ìgbéṣẹ̀ tí wọ́n gbé tí ogun Ìdàhòmì ò fi run wọ́n abbl.) ni a mẹ́nuba nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò wa pẹ̀lú Kábíyèsí Ọba Rev. Evang. John O. Ola Ọdẹ́dòkun Ayinla III, Oníwèéré ti Ìwéré ilé ní Ọjọ́rú, ọjọ́ kẹjọ oṣù Kejìlá ọdún 2021.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: