“Àwọn Ọmọ Markaz Ṣà Fún Debates 😳 | Kí Ló Dé? Ìtúpalẹ̀ Kíkún
Автор: Echo of Truth TV
Загружено: 2026-01-06
Просмотров: 894
Описание:
Nínú fídíò yìí, a ṣàlàyé kí ló dé tí àwọn Ọmọ Markaz fi máa ń ṣàfúnni sí debates, àti àbájáde tí irú rẹ̀ lè ní lórí ẹ̀sìn àti ìwà Musulumi.
Ọ̀rọ̀ yìí kún fún ìmòràn, ìkìlọ̀, àti ẹ̀kọ́ tó yẹ kí gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ Markaz àti Musulumi gbọ́.
🎙️ Ohun tí ẹ ó rí nínú fídíò yìí:
Itumọ̀ debates lábẹ́ ẹ̀sìn Islam
Àǹfààní àti ewu debates
Ìmòràn fún Ọmọ Markaz ní àkókò yìí
👉 Ẹ jọ̀ọ́:
👍 Like
💬 Comment (kí ni èrò yín?)
🔔 Subscribe & turn on notification
Kí Allah tọ́ wa sí ọ̀nà òdodo 🤲
#OmoMarkaz
#IslamicDebate
#YorubaIslamic
#MarkazStudents
#IslamicReminder
#DawahYoruba
#MuslimNigeria
#IlorinIslam
#IslamicDiscussion
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: