ILE IRAN LO WA NIDI IGBESUNMOMO L'ORILEEDE NIGERIA - ASOJU ILE ISRAEL FREEMAN LO SORO SOKE BEE
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-03-08
Просмотров: 10239
Описание:
ILE IRAN LO WA NIDI IGBESUNMOMO L'ORILEEDE NIGERIA - ASOJU ILE ISRAEL FREEMAN LO SORO SOKE BEE
Ilẹ Iran lo wa nidi igbesunmọmi l'orilẹede Naíjíríà - Aṣoju ilẹ Israel Freeman lo sọrọ soke bẹẹ
Tinubu jẹni ire ni o laduru eebu ti mo bu pẹlu abuku ti mo fi kan sibẹ o fori ji mi, o fun mi lominira taba wa ri ẹni to ni bi mo ti satilẹyin fun o daa, a jẹ pe alaimoore ẹda niiru ẹni bẹẹ. Sunday Igboho lo sọrọ soke bẹẹ.
Orileede Nàìjíríà si ma bori awọn agbesunmọmi o, boti le jẹ wọn sekolu ni ipinle Borno laipe - Tinubu lo soro ikiya náà fun awon ologun be.
Awọn aráàlú kọminu lori bi wọn se tun f'owó kun owó epo bẹntiroolu, Ileesẹ ifọpo Dangote yin owó epo bẹntiroolu ti ẹ sókè sí N995 ni jala epo kan
O dojú ẹ o, Awọn Agbesunmọmi tun ji èèyàn mẹwàá gbe salọ nipinlẹ Kwara
Ọdún Ọba Onpetu gbogbo ilẹ Ijeru dun ogbọngbọn kan si o fun bi Kabiesi se jawe oye Asiwaju gbogbo ilẹ Ijeru Kingdom le alagba Isaac Adebayo Akinkunmi lori
“Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí”
“The Voice of Yoruba Worldwide”
DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis.
We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada.
Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: