OLOGUN NIGERIA O LE BORI AWON AGBEBON, IDI REE TI MO FI NI KI IJOBA DUNAAADURA PELU WON - GUMI SORO
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2025-12-10
Просмотров: 9132
Описание:
OLOGUN NIGERIA O LE BORI AWON AGBEBON, IDI REE TI MO FI NI KI IJOBA DUNAAADURA PELU WON - GUMI LO SO BE
Ológun Nàìjiríà kò lè borí àwọn agbébọn, ìdí rèé tí mo fi ní kí ìjọba dúnàádúrà pẹ̀lú wọn - Sheikh Gumi lo so be.
Oluremi Tinubu bá Gomina Adeleke wí bí ìyá ṣe ń bọ́mọ wí ni o, ìwà wèrè la fi ń wo wèrè ni aya ààrẹ náà hù sí gómìnà.
Olubadan figbeta, ṣàlàyé ìdí e tó fi nira láti dipò Ọba mú, ju ipò Gómìnà lọ, bakan náà lo pé fún ṣíṣí àwọn bodè Nàíjíríà padà
Idasilẹ Ọlọpa ipinlẹ, ìdájọ iku fun àwọn Ajinigbe lo le yanjú ọrọ eto-aabo to mẹhẹ - Awọn Adari apa ẹkun gúúsù-ìwọorun ilẹwa lo sọrọ soke bẹẹ
Ọwọ tẹ o, Ileesẹ Ọlọpa nawọ gan olùgbé-ilu Abuja kan fẹsun pe o n fi awọn ohun ijagun oloro ọta ibọn s'ọwọ s'awọn agbebọn ni Zamfara
Haa! O ma se o, èèyàn mẹta ku, ọpọ èèyàn f'arapa ninu ìjàmbá ọkọ to waye loju ọna marosẹ Eko s'ilu Ibadan
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: