Ojú Kálé: Àwọn Ará Ìlú Fi Èrò Wọn Hàn Lórí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Láàrin Lákọ Lábo
Автор: Punch Newspapers
Загружено: 2026-02-14
Просмотров: 60
Описание:
A bá àwọn ará ìlú nípa ohun tí wọ́n rí sí ọ̀rọ̀ ìfẹ́, àti bí wọ́n ṣe gbàgbọ́ nínú ìfẹ́ tó.
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló faraya pé kò sí ohun tó ń jẹ́ ìfẹ́, àti wí pé ẹ̀tàn lásán ni tọkùnrin tobìnrin ń tanra wọn, nígbà tí àwọn mìíràn sì kọ̀ jálẹ̀ wí pé ìfẹ́ wa níbi tí ó wà, ẹni tí kò bá ní in ni kò lè mọ̀.
----- What is this channel all about?
Nigeria's most widely read newspaper featuring breaking news, business, metro, politics, entertainment, sports, multimedia, investigative reports and special features. The online publication has earned its place as the hub of breaking news on the hour in Nigeria.
For the latest news, visit our website: https://bit.ly/2T6gh9m
Follow Punch Newspapers on:
• Facebook: / punchnewspaper
• Twitter: / mobilepunch
• Instagram: / punchnewspa…
#Nigeria #News #PunchNewspapers
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: