Ìmọ̀ ODÙ (Code) | Bí ODÙ Ṣe N Ṣàkóso Ìgbé Ayé Yorùbá
Автор: ObaNyewu
Загружено: 2025-09-13
Просмотров: 87
Описание:
Ẹ káàbọ̀ sí ikànnì yìí 🙏
Nínú fídíò yìí, a máa ṣàlàyé ní kíkún nípa ODÙ (Code) àti pataki ODÙ nínú àṣà Yorùbá. ODÙ jẹ́ ọkàn pàtàkì nínú ìmọ̀ Yorùbá, pàápàá jùlọ nínú Ifá, ìtàn, ìṣe àti ìgbàgbọ́ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá.
A ó:
Ṣàlàyé kí ni ODÙ (Code)
Túmọ̀ ìtàn àti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ODÙ
Ṣàlàyé idi tí ODÙ fi ṣe pátáki nínú àṣà Yorùbá
Fìdí rẹ̀ múlẹ̀ bí ODÙ ṣe ń darí ìgbé ayé, ìpinnu àti ìmọ̀ ẹ̀mí Yorùbá
Fídíò yìí dára fún:
Àwọn tó fẹ́ kọ́ àṣà àti ìtàn Yorùbá
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Ifá
Àwọn tó fẹ́ mọ ìtumọ̀ jinlẹ̀ nípa ODÙ Yorùbá
👉 Má ṣe gbàgbé láti Subscribe, Like, àti Share fídíò yìí kí ìmọ̀ Yorùbá lè tẹ̀síwájú 🌍
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: