E SAN
Автор: DriveTv Yoruba
Загружено: 2026-02-25
Просмотров: 1307
Описание:
E SAN #100M NI KIAKIA TABI KA KO LUYIN, AWON AGBEBON KO LETA SI ARAALU, NIBERU BOJO BA GBA LE
Ilé àṣòfin Amẹ́ríkà gbé èsì ìwádìí nípa ìṣekúpa àwọn Kristẹni ní Naijiria jáde, Wọn ni Nàìjíríà lorílẹ̀èdè tó léwu jùlọ fún kristẹ́nì láti gbé lágbáyé
Haa! Ikunlẹ Abiyamọ o, Awọn Akẹkọ̀ọ́ fasiti LAUTECH mẹfa tofimọ Obìnrin aláboyún kan pade iku ojiji ninu ìjàmbá ọkọ
E gbo se looto ni o, sé lóòótọ́ ni pe ìjọba ìpínlẹ̀ Ogun ti yan Awujale tuntun pẹ̀lú Ifa
El-Rufai n bèèrè fun bilionu kan Naira 1bn lọ́wọ́ ICPC fun tite eto re lójú.
O ma se o, èèyàn mẹwàá lo ha sí panpẹ ìjàmbá ina to sẹyọ nile ìṣàkóso ọkọ ofurufu Muritala Mohammed
Ẹ san ogorun kan millionu N100m ní kíákíá tàbí ká kọ lùyín, Àwọn agbébọn kọ lẹ́tà si aráàlú niberu bojo ba gba lẹ.
Ilẹ̀kùn Al-Jannah máa ń ṣí sílẹ̀, ilẹ̀kùn ọ̀run àpáàdì máa ń wà ní títì pa lásìkò ààwẹ̀ Ramadan - Imaamu Agba fasiti Al-Hikmah lo sọrọ jade bẹẹ lasiko aawẹ Ramadan
Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti kéde rẹ o, wọn kede àfikún owó ọkọ̀ BRT, iye tó jẹ́, ìgbà tí afikun náà yóò bẹ̀rẹ̀ àti ìdí abájọ tófi sàfikún
Повторяем попытку...
Доступные форматы для скачивания:
Скачать видео
-
Информация по загрузке: